Bò Nínú Àjàgà Ìfarawéra Ẹ̀kọ́-Àṣàrò Ọlọ́jọ́ Méje Látọwọ́ Anna LightÀpẹrẹ

Break Free From Comparison a 7 Day Devotional by Anna Light

Ọjọ́ 5 nínú 7

Nígbà ti a bá ṣe àfiwé tí a nímòlárà àìní a gbọ́dọ̀ béèrè: se mo lè mú àwọn ohun tí mo fé kin ní se tí mo bá ṣiṣé kára? Se ohun tón jowú é jé ohun tí Olórun fé se ní ayé e? Bóyá kí a má pá a òwú jíjé àti àfiwé. Bóyá kí a mú tó Olórun ní ìrẹlè kí a bèrè fún ìtọ́sọ́nà Rè.

O lè má lè yí irú ara rè pàdà, àmó se ọ lè máa dín sísanra kù? tí kò mú o ní ayọ? Se o lè tún àpótí ìkó-ǹkan-sí tuntun sí ilé ìdáná kùn láti fún ilé rè ní ìríṣi tó já yoyo. Se o lè sátúnṣe ipò ìbátan kan tí kò dán mọ́rán? Lo fún àmòràn ìgbéyàwó? Síṣe lórí ara e nígbà tí o yìí jé àpón? Se ìwéwèé ètò ìnáwó láti rí ọwó sí í?

Ṣe Olórun lè máa lọ àfiwé àti òwú jíjé láti dárí é sí ònà Tó fẹ lé jẹ kí o lọ?

Èyí gángan lọ ṣẹlẹ̀ sí mi.

Arábìnrin kan tí mo dàgbà pèlú fé dá bí pé o ní gbogbo nńkan. O rewà, o já fáfá, o jé olókìkí láàrín gbogbo èèyàn. Mo rí i pé mo n se àfiwé àra mi mo ń sin rò pé tí mo bá dá bí arábìnrin yìí mí kò ní kórira ẹni tí mo jẹ́.

Nípasẹ àmuyíràá fún ìgbé ayé ọmọgẹ yìí, Mo rí nńkan kan tó dá yàtọ̀ léraléra.

Jésù.

O fí hàn pé Òun ní orísun òkun rè, Ìrètí àti ìgboyà wa láti nńkan tó jù òun fúnra rẹ lọ àti pé ìròyìn ayọ ní pé mo lè ní náà tí mo bá ṣiṣé. Torí náà mo ṣiṣé.

Ọdún díè léyìn náà mo gbà ìpè látódo obìnrin kan tó ń jewó pé òun jowú mi. O sò fún mi, “Mo máa rí ará mi ronú pé tí mo bá lè dá bí Anna, Mo máa féràn ara mi.”

Mo ráye sọ ohun kànnà tí Olórun fí hàn mi fún: “O féé dàbí èmi. O kan fé òmìnira tí o rí, àtìpé ohun ayọ nipé o lè ní í tí o bá ṣiṣé.”

Òtító ní pé, nígbà tí a bá ṣe àfiwé kíákíá tó dá lórí ohun tí a rí ni ìta kò ní mú wá rí ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọkàn tàbí ìgbé ayé ẹni náà.

Kin tó kékọọ yìí, Mo bínú isé Olórun nínú ayé àwọn mìíràn lábẹ́lè, àgàgà tí iṣẹ náà bá jé àṣeyọrí. Mí Kìí ṣe ẹni tó ń sọpé béè kò, Mo jé a òtí. Ní témi, èyí tún burú. Sísàjoyò isé Olórun nínú ayé ẹlòmíràn kò ní gé isé Olórun kúrú nínú ayé e. Kódà, Àìmá sàjoyò pèlú àwon yòókù lè ní ipá lórí ìmúratán Ọlọ́run láti ṣiṣẹ nipasẹ rè. Tí o mbá bínú àṣeyọrí àwọn ayé àwọn mìíràn, borí àjàgà pèlú ìṣírí, kí o sí bèrè lówó ara é ohun tí o nílò kí o tó bèrè isé.

Ṣe nńkan mbè láyé è tí inú kò dún nípa tí o ní àgbàrá yípadà?

Kí pọn dì é lówó láti ṣe ayípadà yìí?

Olúwa, Mo fé mú àwọn àfiwé àti òwú jíjé mi wá sọdọ Yín kin bèrè fún ìtọ́sọ́nà fún ayé mi. Se É dárí mi sí ònà tó yẹ ki lọ? É sí ojú mi si ohun tí È lé máa sọ ní àkókò yìí tí mo mú àwọn ohun yìí tó Yìn wá. E rán mí lówó láti jé ìṣírí sí àwọn yòókù, ní ìmọ pé É féràn mi gégé bí É ṣe féràn èyíkéyìí èèyàn.

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Break Free From Comparison a 7 Day Devotional by Anna Light

Ìwọ́ mọ̀ wípé Ọlọ́rùn pèsè ìgbé ayé ọpọ yantúrú jú èyí tó ń gbé yì lọ, àmọ́ òtítọ́ tó kóro ní wípé ṣíṣe ìfáráwéra fà ọ sẹ́yìn láti lọ sí ipélé tó kan. Nínú ètò kíkà yìí Anna Light hú àwọn ìjìnlẹ̀ òye jáde láti fọ́ àpótí tí ìfáráwéra fi dé àwọ́n àbùdá rẹ, àti ràn ọ lọ́wọ́ láti gbé ìgbésí-ayé òmìnira oún ìgbé ayé ọ́pọ yantúrú tí Ọlọ́rùn tí yà sọ́tọ fún ọ

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Anna Light (LiveLaughLight) fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ lọ sí: http://www.livelaughlight.com