Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Agbára Ìgbágbó
Ohun alágbára kan má n selè nígbà tí a bá gbékèlé Olórun tó kì í se láti lè má gbó ohun Tó bá so nìkan, àmó, gbágbó è. Tó bá gbágbó nínú ohun tí Olórun so pé òtítọ́ ní àtipé ètò Rè fún è a yorí sí àbájáde tó dára jù lo tó lè selè, pé ìgbékèlé yorí sí àlàáfíà àti ìbùkún. Lẹ́yìn tí Màríà bá ángèlì náà pàdé àti juwọ́ sílẹ̀ sí ètò Olórun fún ayé rè, ò bè mọ̀lẹ́bí rè Elisabẹti wò, tó lóyún lónà ìyanu náà lèyín ìgbá tó ní ìrírí àìrọ́mọbí fún odún. Nígbà tí Elisabẹti gbó ìròyìn Màríà tó jé àràmàǹdà, ó kún fún Èmí Mímó àti o polongo, “Ìbùkún ní fún òun tó tí gbágbó pé Olúwa yóò se ìmúṣẹ àwon ìlérí Rè fún un!"
Màríà gbá Olórun gbó nígbà tí Ó so pé Màríà yóò bí Mèsáyá tí a tí n retí tipétipé àtipe Ó búkún rè pèlú àlàáfíà nígbà tí ó lè tí kún fún àníyàn. Ó ní ìdánilójú pé ìbí Olùgbàlà ayé—Olùgbàlà rè—má níyelórí jù èyíkéyìí àdánwò tí òun lè kojú lójú ònà lo. Màríà gbékèlé ètò Olórun àti tẹ̀ síwájú ní gbágbó pé àwon ìlérí Rè yóò wá sí ìmúṣẹ ní ayé rè.
Bí a n se sún mó Kérésìmesì, ronú nípa àbájáde àràmàǹdà tí ìgbágbó Màríà: A bí Omo Olórun! Kí ni Olórun tí sò sórí ayé è tí ó ní láti gbágbó lónìí? Gbékèlé ètò Rè, gbá àlàáfíà Rè ní mimó pé Ó mò èyí tó dára jù lo, àti fojúsọ́nà sí ìbùkún tó ń bọ̀!
Àdúrà: Bàbá, bí mo n se fi àfiyèsí lórí ìbùkún ìbí Jésù, È ràn mi lọ́wọ́ láti túbò di bí Màríà sí. È ràn mi lọ́wọ́ láti dàgbà ní gbékèlé mi àti gbá gbó nínú àwon ìlérí Yín. Mo mò pé ètò Yín fún ayé mi má n yorí sí àbájáde tó dára jù lo tó lè selè. È ràn mi lọ́wọ́ láti ṣàwárí èyíkéyìí àgbègbè tí àìnígbàgbọ́ nínú ayé mi, àti È fún mi ní ìgbágbó pé È ń ṣiṣẹ́ lónà tí mi kò lè rí. Mo yan láti gbékèlé Yín lónìí!
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More