Bibeli Fun Awon OmodeÀpẹrẹ
OLORUN DA OHUN GBOGBO! Nigbati Olorun da okunrin akoko, Adamu, ogbe inu ogba Edeni pelu aya re, Efa. Won wa ninu ayo pipe won si ngboran si Olorun won si ngbadun iwapelu re titi ojo kan …
“Se Looto ni Olorun ni ki emase je ninu gbogbo igi?” Ejo bi Efa. “Ale je ninu gbogbo igi eleso ayafi okan,” Odaa lohun. “Sugbon bi aba je tabi fowokan eso yen, awa yio ku.” “Enyin koni ku,” Ejo wi. “Enyin yio dabi Olorun.” Efa fe eso igi na. Ogbo si ejo lenu osi je eso na.
Lehin igbati Efa saigboran so Olorun, Omu Adamu lati je eso na. Adamu ibati so wipe, “Rara O! Emi ki yio saigboran si oro Olorun.”
Nigbati Adamu ati Efa se, won ri wipe awon wan i ihoho. Won mu ewe lati fi bo ihoho won, won fi ara pamo kuro niwaju Olorun.
Ni asale, Olorun wa sinu ogba. O mo ohun ti Adamu ati Efa tise. Adamu tie bi si Efa. Efa si ti ebi si ejo. Olorun wipe, “Egun ni fun ejo. Obirin yio ni ijiya nigbati o ba bi omo.” “Adamu, nitoripe o se, afi ile bu fun o pelu egun ati osusu. Iwo yio jiya pelu oogun ki oto jeun ojo.”
Olorun mu Adamu ati Efa kuro ninu ogba didara. Nitoriwipe won se, aya won kuro lodo Olorun alaaye!
Olorun da ida ina lati le won jade. Olorun se aso alawo fun Adamu ati Efa. Nibo ni Olorun timu awo ara eranko wa?
Laipe ojo, Adamu ati Efa bimo. Omokunrin akoko, Kaini, je agbe. Omokunrin ekeji, Abeli, je oluso agutan. Ni ojo kan Kaini mu ewebe wa fun Olorun gegebi ebun. Abeli pelu mu awon agutan to joju wa fun Olorun gegebi ebun. Olorun tewo gba ebun Abeli.
Olorun ko tewogba ebun Kaini. Kaini banuje. Sugbon Olorun wipe, “Bi iwo base rere, a o ni gba o bi?”
Ibinu kaini ko kuro. Lehin igbakan o koju ija si Abeli ninu oko- osi paa.
Olorun wi fun Kaini pe. “Nibo ni Abeli aburo re wa?” “Emi komo,” Kaini pa iro. “Emi je oluso agutan re bi?” Olorun fi iya je Kaini, kose agbe mo, o so di alarinkiri.
Kaini lo kuro niwaju OLUWA. Omu omobinrin Adamu ati Eefa ni aya. Won si li ebi. Laipe, awon omo-omo ati omo-omo-omo kaini kun ilu ti o ko.
Sugbon, awon iran Adamu ati Efa dagba ni kiakia. Ni aiye igba yen, awon eniyan gbe pe ju ojo oni lo.
Nigbat o bi omokunrin re, Seti, Efa wipe, “oLorun fi Seti fun mi lati ropo Abeli.” Seti je eniti o beru Olorun osi gbe igbe aye mejila ledegberun. Oni omo pupo.
Ninu aiye, awon eniyan buru si bi iran kan se ntele omiran. Nigbehin, Olorun pinu lati pa eniyan run ati awon eranko ati eiye oju orun. Inu Olorun kodun nitori nitori wipe oda eniyan. Sugbon eniyan kan te Olorun lorun ...
Eni na ni Noa. Iran Seti ni, Noa je olododo ati olooto. O rin pelu Olorun. O ko awon omokunrin re meta lati gboran si Olorun. Nisiyii Olorun pinu lati lo Noa ni ona ti o dara!
Opin
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bawo ni gbogbo rẹ ṣe bẹrẹ? Nibo ni a ti wa? Kini idi ti irora pupọ wa ni agbaye? Ṣe ireti eyikeyi wa? Njẹ aye wa lẹhin ikú? Wa awọn idahun bi o ti ka itan otitọ yii ti aiye.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Bibeli fun Awọn ọmọde, Inc. fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://bibleforchildren.org/languages/yoruba/stories.php