Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Pàṣípààrọ̀ Ńlá
Jésù wá sáyé láti fún wa làwon èbùn ìtéwó gba, àlàáfíà, ìwòsàn, àti ìdáríjì, àmó àwon èbùn wònyí kì í se olówó pọ́ọ́kú. A kò lè láǹfààní ohun tí Jésù wá láti pèsè fún ara wa, àti pẹ̀lú ẹ̀mí ìmoore, a kò ní láti. Olórun báyìí téwó gba wa, sùgbón kì í se nítorí ìwà dáradára wa, àmó nítorí Jésù san iye owó nípasè nírìírí ìkọ̀sílè nlá nítorí wa. Jésù pinnu láti kú láti bò èsè wa, ségun ikú, àti mú ìyè wá fún wa. Wòlíì Aísáyà pè àwon èsè wa ni “àwon ìrélànàkọjá” àti “àwon àìṣedéédé” - ní pàtàkì àwon ìwà òdaràn wa àti àwon ìwà burúkú wa. Àwon èsè yen da gbèsè sí wa lorùn tí akò lè san láé, àmó Jésù, nínú ìjépípé Rè, lè se. Jésù yàn kí a bí sínú ayé nibi tí a yóò tí dá àpá sí ati fọ́ ọ túútúú, Ó mú àlàáfíà àti ìwòsàn wá fún wa.
Àsotélè ní Aísáyà 53 ṣàpèjúwe Pàṣípààrọ̀ nlá tí Olórun: ìgbé ayé Jésù fún gbogbo ìgbé ayé wa. Jésù mò iye Kérésìmesì, àtipe Ó téwó gba a kí a lè téwó gba Òun àti ìyè àìnípẹ̀kun Tó sètò sílẹ̀ fún wa. Bó n se sàjoyò àkókò yìí, má gbàgbé: A lè ní nìkan ní ìdáríjì, ní ìwòsàn, àti dòmìnira nítorí Jésù yàn Kérésìmesì.
Àdúrà: Jésù, mi kò lè dúpé lówó Yín tó láé fún sisan iye tó bò gbèsè mi. Má tí sonù lòtító láìsí Yín. Mo se ìjosìn Yín gégé bí Àlàáfíà mi, Oníwòsàn mi, àti Olùgbàlà mi! È se fún yíyàn Kérésìmesì. È rán mi lówó láti gbá gbogbo Té mú wá láti fún mi, àtipe È rán mi lówó nígbà náà láti pín àwon èbùn náà pèlú ayé láyíká mi.
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More