Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
“Sar Shalom”
Nípasè wòlíì Aísáyà, Olórun fi hàn pé a yóò bí omo kan tá yóò pé ni Omo Aládé Àlàáfíà. Ní Hébérù, òrò fún “Omo aládé” ("sar”) tọ́ka sí aṣáájú tabi olórí, àtipe òrò fún "àlàáfíà” ("shalom”) túmò sí “kíkún délèdélè." Nígbà tí Jésù wá sayé,Ó wá láti samònà ayé tótí túká sibi tí a yóò tí so wa dódindi padà. Ó wá láti mú wa padà bá Olórun, n tẹ́ afárá sí àlàfo tí èsè wa dá. Jésù wá láti máratu àwon àníyàn wa àti fún wa lokàn tó jíire. Àlàáfíà náà Tó mú wá sayé ní Kérésìmesì fún wa láàyè láti nítẹ́lọ́rùn àti simi nínú Rè ohun yòówù wàhálà tó yí wa ká.
Ohun yòówù tí ó lè má dójú kò ní àsìkò yìí —àìsàn, ìbásepò tó túká, ìsoríkọ́, tàbí ìdánìkanwà—gbà àlàáfíà Jésù láàyè’ láti tpù ó nú nibi tó wá gan-an. Ó kò ní láti dé òpin ìsásókèsódò láti nírìírí jijé òdindi. Jésù fé fi ìdákẹ́jẹ́ẹ́ sèmí rè pèlú ifé Rè àti fi ìjépípé sí ìgbékèlé rè nínú Rè. Ó lè fópin sí ìjì yìí pátápátá nínú Rè.
Àdúrà: Jésù, E seun pé E wá láti mú àlàáfíà wà. Mo mò pé lónìí mo lè simi ninú Yín, ohun yòówù tí mo n la kojá. Ìgbàkígbà tí èrù tàbí àjàgà bá halẹ̀ mọ́ àlàáfíà mi, E ràn mi lówó láti sáré lo sí ààbò nínú Yín. E darí èmí mi sínú èkúnréré tó wà nílẹ̀ nínú Yín.
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More