Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Mú gbára dì fún Ète kan
Àkókò tí tó fún ìllérí àkókó Olórun láti wa sí ìmúse. À yóò ségun èsè láìpe títí láé, àmó làkókó náà, a ní láti gbé Olùgbàlà sínú ìyá Rè. Se ó lè fojú inú wò bí Olórun ma se yára gágá sí bí Ò see rán ángèlì láti òrun láti fi ètò Rè hàn sí Màríà? Èyí jé àsìkò ẹgbẹ̀rún ọdún nínú sisé!
Ronú nípa Màríà: òdó àti onírẹ̀lẹ̀ sùgbón rí ojú rere Olórun. Nígbà tí Ó rán ángèlì náà sí ódó rè, Ó rán an pèlú àwon òrò ifé. Ó jé kí ó mò pé a tí yàn àtipe kò nìdí láti bèrù. Kío tó ní àkókò láti siyèméjì tàbí láti jé kí àìsí ìfọ̀kànbalẹ̀ yó wolé, Olórun fún Màríà ní ìdánilójú tó ní-lò láti kẹ́sẹ járí, ète Rè fún ayé rè.
Bí Kérésimèsì ṣe ń sún mọ́lé fi ara rè sínú bàtà Màríà àti ronú lórí àkókò yìí. Ronú nípa bí àràmàǹdà, bóyá Kódà wá pò lápòjù, tó je fún un láti sàwárí débi ète tí Olórun-fún un. Ó se pàtàkì láti mò pé gégé bí Ó se ní ète àtọ̀runwá fún Màríà, Olórun ní ète àtọ̀runwá fún ó. Gégé bí Ó tí yàn Màríà àtipe fi ohun sábẹ́ ìtọ́jú rè pèlú àwon ètò tó tóbi, Ó tí yàn ìwo náà àtipe fohun onìyanu kan sábẹ́ ìtọ́jú rè! Béèrè lówó Olórun láti se ìfihàn ohun Tó sèdá rè láti se, àti ní ìdánilójú pé Yóò mú ó gbára dì láti se.
Àdúrà: Bàbá, Ẹ ṣeun fún èbùn Yín tí Jésù. E see fún yíyàn obìnrin bí Màríà láti mú U wá sínú ayé. È lo Màríà bí ohun èlò fún ìyanu Yín tó tóbi ju lo. È se fún fifún mi ní ète àtọ̀runwá. È ràn mi lówó láti paroro, láti wá Yín, àti láti túbò mò Yín láàárín àkókò yìí. È lo ìgbà yìí láti túbò se ìfihàn nípa ète Yín fún mi bí mo se fí àfiyèsí lórí ète Kérésìmesì.
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More