Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
A Tí Mú Òdodo Padà Bò Sípò
Nínú àsotélè kan tá rí ní Sekaráyà 9, Olórun se ìllérí pé Oba ojọ́ iwájú yóò wá pèlú ìgbàlà àti mímú Òdodo Rè wá. Èyí túmò sí pé ní Kérésìmesì, Olórun mú “ òdodo Rè wá fún wa” sí ayé ni ènì tí Jésù. Èyí gan-an ni ayé ní-lò (àti sí i máa ní-lò). Ní Róòmù 3:10, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sàpèjúwe ipò tó bani nínú jẹ́ tí àwa ènìyàn: “Kò sí olódodo, rárá, kò sí ènìkàn.” Gbogbo wá mbe ní ipò kaánnà, a bí wa pèlú àdánidá èsè àtipe a kò lè mú arawa jé olódodo. Àmó ní Róòmù 1:17, Pọ́ọ̀lù wí pé, ”Olódodo yóò gbé nípa ìgbàgbó.” Èsìn Kristeni kì í se nípa niní étọ̀ọ́ òdodo, ó jé nípa gbígbà òdodo Jésù “nípa ìgbàgbó.” kì í se nípa ènì tí a jé, ó jé nípa ènì tí Ó jé.Lèyín ìgbà tí a bí Jésù, Ó tésíwájú láti máa gbé ní òdodo ní gbogbo ojó ayé Rè. Ó jé pípé, Ó ñ sún mò Olórun tímótímó àtipe Ó ñ tè lé ètò Bàbá Rè. Lórí igi àgbélébùú, Ó se gbígbé nñkan. 2 Kọ́ríńtì 5:21 wí pé, “Nítorí tíwa Olórun se E ní èsè Òun tí kò mò èsè, kí a bá lè di òdodo Olórun nínú Rè.” Nígbà tí Jésù kú fún wa, Ó gbà gbogbo áìṣòdodo wa wò àti Ó sí fi kú pa wón, Ó sí fún wa ní òdodo àti àjose tímótímó Rè pèlú Olórun.
Àdúrà: Bàbá, È kún fún oore ọ̀fẹ́ ìyàlẹ́nu! Mo gbá òdodo Yín lónìí nípa ìgbàgbó Nínú Omo Yín, Jésù. Mo mò pé inú Yín dùn pèlú mi nítorí ohun tí Jésù tí se fún mi. È seun, Jésù fún mi ní ìgbẹ́mìíró. È fún mi lókun pèlú ìdánilójú pé mo wa lààbò nínú Òdodo Yín. È ràn mi lówó láti rántí pé mi kò létọ̀ọ́ sí i fún ara mi kí n báa lè sìn Yín pèlú ìrẹ̀lẹ̀-ọkàn àti ẹ̀mí ìmoore ní gbogbo ojó ayé mi
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More